Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwọn Júù mọ irú ìgbé ayé tí mo ń gbé láti ìgbà èwe mi, láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé mi ní orílẹ̀-èdè mi àti ní Jerúsálémù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:1-11