Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọn wọ yẹ̀wù lọ, wọn bá ara wọn jíròrò, wọ́n sọ pé, “Ọkùnrin yìí kò ṣe nǹkan kan tí ó yẹ sí ikú tàbí sì ẹ̀wọ̀n.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:22-32