Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìkóríta yìí Fẹ́sítúsì kọ dí àwíjàre Pọ́ọ̀lù, ó wí lóhùn rara pé, “Pọ́ọ̀lù, orí rẹ dàrú; ẹ̀kọ́ àkọ́jù rẹ ti dà ọ́ ní orí rú!”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:21-32