Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni àwọn Júù ṣe gbá mi mú nínú tẹ́ḿpílì, tí wọ́n sì ń fẹ́ pá mí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:16-26