Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àgírípà ọba, inú èmi tìkárami dùn nítorí tí èmi yóò wí ti ẹnu mi lónìí níwájú rẹ, ní ti gbogbo ẹ̀sùn tí àwọn Júù fi mi sùn,

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:1-7