Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi sì wí pé, ‘Ìwọ ta ni, Olúwa?’“Olúwa sì wí pé, ‘Èmi ni Jésù tí ìwọ ń ṣe inúnibíni sí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:10-19