Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nínú irú ìrìnàjò yìí ní mo ń bá lọ sí Dámásíkù pẹ̀lú ọlá àti àṣẹ ikọ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn olórí àlùfáà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:3-18