Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyi ni mo sì ṣe ni Jerúsálémù. Pẹ̀lú àṣẹ tí mo tí gba lọ́dọ̀ àwọn olórí àlùfáà, mo sọ àwọn púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn mímọ́ sí inú túbú, nígbà tí wọ́n sí ń pa wọ́n, mo ní ohùn sí i.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:1-13