Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn olùfiṣùn náa dìde, wọn kò ka ọ̀ràn búburú irú èyí tí mo rò sí i lọ́rùn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:13-27