Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà àwọn Júù fi sùn nígbà tí mo wà ni Jerúsálémù, wọ́n ń fẹ́ kí èmi ó dá a lẹ́bi ikú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:12-25