Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ijọ́ mélòó kan, Àgírípà ọba, àti Béníkè sọ̀kalẹ̀ wá sì Kesaríà láti kí Fẹ́sítúsì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:3-18