Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Júù pẹ̀lú sì fi ohùn sí i wí pé, ní òtítọ́ bẹ́ẹ̀ ni nǹkan wọ̀nyí rí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:1-19