Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí àwa rí ọkùnrin yìí, ó jẹ́ oníjàngbàn ènìyàn, ẹni tí ó ń dá rúkèrúdò ṣílẹ̀ láàrin gbogbo àwọn Júù tí ó wà ní gbogbo ayé. Òun ni aṣáájú búburú kan nínú ẹ̀yà àwọn Násárénè:

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:2-8