Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ibi gbogbo àti ní ọ̀nà gbogbo, Fẹ́líkísì ọlọ́lá jùlọ, ní àwa ń tẹ́wọ́gbà á pẹ̀lú ọpẹ́ gbogbo.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:1-9