Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí kò ṣe tí gbolóhùn kan yìí, tí mo kégbe rẹ̀ ṣíta nígbà tí mo dúró láàrin wọn: ‘Èyí ni tìtorí àjíǹde òkú ni a ṣe ba mi wíjọ́ lọ́dọ̀ yín lóni yìí!’ ”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:12-22