Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ní wọ́n kò lè fi ìdí ẹ̀sùn múlẹ̀ níwájú rẹ, èyí tí wọn fi mí sùn sí nísinsìn yìí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:11-18