Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ pẹ̀lú sì ní òye rẹ̀ pé, ìjejìlá ni mo lọ sí Jerúsálémù láti lọ jọ́sìn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:6-18