Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó dúró tì Pọ́ọ̀lù sì wí pé, “Ìwọ́ ń gan olórí àlùfáà Ọlọ́run?”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:1-10