Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ní, “Èmi yóò gbọ ẹjọ́ rẹ, nígbà tí àwọn olùfiṣùn rẹ pẹ̀lú bá dé.” Ó sì paṣẹ pé kí wọn pa Pọ́ọ̀lù mọ́ ní abẹ́ àmójútó àwọn olùsọ́ ní gbọ̀ngán-ídájọ́ ààfin Hẹ́rọ́dù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:27-35