Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà yìí ni Ananíyà olórí àlùfáà pàṣẹ fún àwọn tí ó dúró tí Pọ́ọ̀lù pé, kí wọn ó gbá a lẹ́nu.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:1-8