Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ọmọ arabínrin Pọ́ọ̀lù sí gbúrò ìdìtẹ̀ wọn, ó lọ, ó sì wọ inú àgọ́ àwọn ológun lọ, ó sì sọ fún Pọ́ọ̀lù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:10-24