Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru ijọ́ náà Olúwa dúró tì Pọ́ọ̀lù, ó wí pé, “Mú ọkàn le! Bí ìwọ ti jẹ́rìí fún mi ní Jerúsálémù, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò lè ṣàìjẹ́rìí ni Róòmù pẹ̀lú.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:6-13