Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n sí tí fi okùn-ọṣán dè é, Pọ́ọ̀lù bí balógun ọ̀rún tí ó dúró tì í pé, “Ó ha tọ́ fún yín láti na ẹni tí i ṣe ará Róòmù ni àìdálẹ́bi bí?”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:19-28