Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi sì wí pé, ‘Olúwa, àwọn ènìyàn wọ̀nyí pàápàá mọ̀ pé èmi ti lọ láti inú sínágọ́gù kan sí èkejì láti máa sọ wọ́n sínú túbú àti láti máa lu àwọn tí ó gbà ọ́ gbọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:16-29