Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí a sì ti parí àjò wa láti Tírè, àwa dé Pítólémáì; nígbà ti a sì kí àwọn ará, a sì bá wọn gbé ní ijọ́ kan.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:1-14