Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ọjọ́ méje sì fẹ́rẹ̀ pé, tí àwọn Júù tí ó ti Éṣíà wá rí i ni tẹ́ḿpílì, wọ́n rú gbogbo àwọn ènìyàn sókè, wọ́n nawọ́ mú un.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:20-30