Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn láti Kéṣáríà bá wa lọ, wọ́n sì mú wa lọ sí ilé Múnásónì ọmọ-ẹ̀yìn àtijọ́ kan ara Sàìpúrọ́sì, lọ́dọ̀ ẹni tí àwa óò dé sí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:12-22