Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a sì tí wà níbẹ̀ lọ́jọ́ púpọ̀, wòlíì kan tí Jùdíà sọ̀kalẹ̀ wá, tí a ń pè ní Ágábù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:9-17