Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa sì síkọ̀ láti Fílípì lọ lẹ́yìn ọjọ àkàrà àìwú, a sì dé ọ̀dọ̀ wọn ní Tíróáṣì ni ijọ́ méje.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:1-9