Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú wọn sì bàjẹ́ jùlọ fún ọ̀rọ̀ tí ó sọ pé, wọn kì yóò rí ojú òun mọ́, wọ́n sì sìn ín títí dé inú ọkọ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:28-38