Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì tí wí nǹkan wọ̀nyí, ó kúnlẹ̀, ó sì bá gbogbo wọn gbàdúrà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:26-38