Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà mo pè yín ṣe ẹlẹ́rìí lónìí yìí pé, ọrùn mi mọ́ kúró nínú ẹ̀jẹ̀ ènìyàn gbogbo.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:19-35