Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí mo ń sọ fún àwọn Júù, àti fún àwọn Gíríkì pẹ̀lú, ní ti ìrònúpìwàdà sí Ọlọ́run, àti ti ìgbàgbọ́ nínú Jésù Kírísítì Olúwa wa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:12-27