Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì tí la apá ìhà wọ̀nyí kọjá, tí ó sì ti fi ọ̀rọ̀ pupọ gbà wọ́n ní ìyànjú, ó wá sí ilẹ̀ Gíríkì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:1-5