Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo ti ń fi ìrẹ̀lẹ̀ inú gbogbo sin Olúwa, àti omijé púpọ̀, pẹ̀lú ìdánwò, tí ó bá mi, nípa rìkíṣí àwọn Júù:

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:10-23