Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu sì yà wọ́n, wọn ń wí fún ara wọn pé, “Ǹjẹ́ ara Gálílì kọ́ ni gbogbo àwọn tí ń sọ̀rọ̀ wọ̀nyí jẹ́?

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:3-9