Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ará, èmí lè sọ fún yin pẹ́lú ìgboyà pé ní ti Dáfídì baba ńlá kú, a sì sin ín, ibojì rẹ̀ sì ń bẹ lọ́dọ̀ wa títí di òní yìí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:21-39