Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A yóò sọ òòrùn di òkùnkùn,àti òṣùpá di ẹ̀jẹ̀,kí ọjọ́ ńlá àti ọjọ́ ológo Olúwa tó dé.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:12-22