Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(àti àwọn Júù àti àwọn tí a tipa ẹ̀sìn sọ di Júù); Àwọn ara Kírétè àti Árábíà; àwa gbọ́ tí wọ́n sọ́rọ̀ iṣẹ́ ìyanu ńlá Ọlọ́run ni èdè wa.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:1-12