Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ọjọ́ Pẹ́ńtíkọ́sítì sì dé, gbogbo wọn fi ọkàn kan wà ní ibìkan.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:1-8