Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ti ẹ̀yin mú àwọn ọkùnrin wọ̀nyí wá, wọn kò ja ilé òrìṣà lólè, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ṣọ̀rọ̀-òdì ṣí òrìṣà wa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:28-41