Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì tí rán méjì nínú àwọn tí ń ṣe ìránṣẹ́ fún un lọ ṣí Makedóníà, Tímótíù àti Érásítù, òun tìkararẹ̀ dúró díẹ̀ ní ilẹ̀ Éṣíà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:19-29