Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìròyìn yìí sì di mímọ̀ fún gbogbo àwọn Júù àti àwọn ará Gíríkì pẹ̀lú tí ó ṣe àtìpó ní Éfésù; ẹ̀rù sì ba gbogbo wọn, a sì gbé orúkọ Jésù Olúwa ga.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:7-27