Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn méje kan sì wà, tí wọn ń ṣe bẹ́ẹ̀, àwọn ọmọ ẹnìkan tí a ń pè ni Síkẹ́fà, Júù, tí í ṣe olórí àlùfáà gíga.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:7-16