Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tóbẹ́ẹ̀ tí a fi ń mú aṣọ àti ìbàǹtẹ́ ara rẹ̀ tọ àwọn ọlọ́kùnrùn lọ, àrùn sì fi wọ́n sílẹ̀, àwọn ẹ̀mí búburú sì jáde kúrò lára wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:8-17