Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì bẹ̀rẹ̀ ṣí fi ìgboyà sọ̀rọ̀ ni Sínágọ́gù: nígbà tí Àkúílà àti Pìrìskílà gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, wọ́n mú un sọ́dọ̀ wọ́n sì túbọ̀ sọ ọ̀nà Ọlọ́run fún un dájúdájú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:18-28