Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì gbé ọjọ́ díẹ̀ níbẹ, ó lọ, ó sì kọjá lọ láti Gálátíà àti Fírígíà, ó mú gbogbo àwọn ọmọ-ẹ̀yìn lọ́kàn le.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:16-25