Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn Gíríkì sì mú Sósìténì, olórí ṣínágógù, wọ́n sì lù ú níwájú ìtẹ́ ìdájọ́. Gálíónì kò sì bìkítà fún nǹkan wọ̀nyí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:10-22