Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n Épíkúrè àti tí àwọn Sítííkì pàdé rẹ̀. Àwọn kan si ń wí pé, “Kín ni aláhesọ yìí yóò rí wí?” Àwọn mìíràn sì wí pé, “Ó dàbí ń wàásù Jésù, àti àjíǹde fún wọn.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:16-20