Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn arákùnrin rán Pọ́ọ̀lù jáde lọ́gán láti lọ títí de òkun: ṣùgbọ́n Sílà àti Tímótíù dúró ṣíbẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:5-15